Haa! What Ifa said about Tinubu on Feb 25th

Ha! Terrific message from Ifa Agboniregun to Asiwaju Bola Ahmed Tinubu. Ifa so pe.. ..... Imagine this But why is this? And Ifa is has been Accurate and most precise He says.. Gedegbe lowo nyo ju Ori Iwaju opon o gbo Eyin opon o gba Olumu Otun, olukanran OSI Aarin opon Ita orun Adifa fun Bola Ahmed omo Tinubu Nigbati awon PDP, Labour Party, ati awon amugbalegbe pejo ni nibi gbogbo Lati fenu obu wi tire Won ni ki Bola Ahmed Omo Tinubu maa so wipe: Osalala loruko ti a pe aye Obekisi Jana loruko esu Odara Adifa fun rikisi awon aje PDP ati awon aje Labour ati awon aje alatako ibi gbogbo, Imo enini kii dojo ale Emo ajao ki ja Ajaro ni ti adan Eja kii sere erupe dojo ale Ajantuka ni ti agbaarin, Ibi ti Ojo ba ti ba Ojo Ibe lo maa pasi Gbogbo rikisi, efufulele ma dawon nu Efufulele Gbogbo abamoda won, efufulele Maa dawon nu, efufulele. Sugbon nipa ti Bola Omo Tinubu Kenke loruko ti a pori Atari pakata loruko ona Ona la, Bola Omo Tinubu fe wo Aso Rock Omo.Abibatu Mogaji fe di Olori Orile Ede Nigeria Ona laaaaaaaaa Aboru boye ni tifa o...... Aseyori ni ti Oorun Gedegede lowo yo jori Ogagan ona lalake nso Awise ni Tedumare Oro talagemo ba da Ni orisa oke ngba Sise sise ni ti Ilakose Oti ri be Oti se be Bola Ahmed omo Tinubu Oo ma bori ota Oo ma rehin odi. Gedegbe lowo nyo jori Aseyori ni tie Emi ko oo Ifa loso be Signed Wale Ojo- Lanre Member, Special Ops / New Media , APC PCC Usi- Ekiti.

Comments

Popular posts from this blog

OMG ! Obasanjo releases another bombshell against Tinubu

Here is permanent solution to STROKE

Why women are useless beings walahi ! By Wale Ojo - Lanre